Everyday, so God...
Bacause of you. I dey live, I dey breath, I dey eat
So, I wanna have some talk with you

Orun, silekun I wanna have some talk, [with] you o (2xe)

Nitori re mose n lola
Nitori re mose n s'oge
Nitori re mose n ra moto

Mowole, M'oboluwa mi soro

Nitori re mose wa laye
Nitori re mose n woso sara
Nitori re moji l'owuro
Mow'aye mi lode ye

A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro

Nitori re mose n gbo iroyin ayo
Lais'owo laisi nkankan
Iya oni, layoola o
B'oluwa tiwi, be naa lori

Jiji moji lowuro
Moji si inu ipese re
Ayo at'alafia ye ye

O, o o oni pe ki n ma se beru

A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro

Melo la fe so
Melo lo si n bowa
Melo la fe so, eh
Melo lo si n bowa

Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh
Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh
Ninu iponju, Ninu idamu,
B'ebi ba n p'ona
Mawole, maboluwa mi soro

B'emi o le yan
Baye ba foju dimi
B'emi o le ni
Mawole, maboluwa mi soro

A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro

Ninu iponju, Ninu idamu,
B'ebi ba n p'ona
Mawole, maboluwa mi soro
Mioni foju sunkun mo o
Aye loja, oh oh... Orun... Orunile
And that's fine by me... eh eh...
Oh... ye ye... bring it down... oh oh...

Comments